Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Oṣù Kẹ́rin 2025 Abala Òwúrọ̀ Sátidé Abala Òwúrọ̀ SátidéAbala Òwúrọ̀ Sátidé ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2025. Dallin H. OaksÌmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè GbogbogbòÀàrẹ Oaks gbé àwọn Aláṣẹ Gbogbogbo, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóye Gbogbogbò ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn kalẹ̀ fún ìbò ìmúdúró. Jared B. LarsonÌròhìn Ẹ̀ka Jíjẹ́rí Ìṣírò ohun-ìní Ìjọ, 2024Jared B. Larson ka jíjẹ́rí ìṣiro ohun-ìní Ìjọ. Jeffrey R. HollandBíi Ọmọ KékeréAàrẹ Holland kọ́ni ní pàtàkì dídàbí ọmọ kékeré kí a ba lè wọ ìjọba Ọlọ́run. Camille N. JohnsonÌmúláradá Níti Ẹ̀mí nínú Rẹ̀Ààrẹ Johnson kọ́ni pé a lè jẹ́ ìmúláradá nípa ti ẹ̀mí bí a ṣe ndúró de ìwòsàn ti ara àti ti ẹ̀dùn-ọkán. Ronald A. RasbandNí Ìwajú Wa GanganṢíṣe àkíyèsí pé Olúwa nyára kánkán ṣe iṣẹ́ Rẹ̀, Alàgbà Rasbánd tún ìdàgbà Ìjọ nínú àwọn ọmọ ìjọ, míṣọ̀n, tẹ́mpìlì, àti ìtiraka ẹ̀kọ́ sọ. Quentin L. CookÈtùtù Jésù Krístì Npèsè Ìgbàlà Ìgbẹ̀hìnAlàgbà Cook lo àpẹrẹ ti kẹ̀kẹ́ àfọwọ́yí àwọn olùlànà láti kọ́ni pé Jésù Krístì yíò gbà wá là kúrò nínú àwọn ìjì ayé. Ricardo P. GiménezÌfẹ́ Mi fún Olùgbàlà Ni “Èrèdí” MiAlàgbà Giménez kọ́ni nípa pàtàkì síso àwọn ìṣe wa pọ̀ mọ́ ìfẹ́ wa fún Jésù Krístì. Henry B. Eyring“Súnmọ́ ọ̀dọ̀ Mi”Ààrẹ Eyring kọ́ni pé a lè súnmọ́ Olùgbàlà nípa gbígbàdúrà, fífi etí sílẹ̀ fún ìtọnisọ́nà, àti sísin àwọn ẹlòmíràn. Abala Ọ̀sán Ọjọ́ Sátidé Abala Ọ̀sán Ọjọ́ SátidéAbala Ọ̀sán Sátidé ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2025. Neil L. AndersenṢíṣìkẹ́ Ìgbésí AyéAlàgbà Andersen kọ́ni nípa ìwàmímọ́ ayé àti pàtàkì ṣíṣìkẹ́ àti dídá ààbò bò ó. Steven J. LundÀṣẹ Àtọ̀runwá, Àwọn Ọ̀dọ́mọkùnrin Gíga JùlọÀàrẹ Lund kọ́ni nípa àwọn ojúṣe àwọn tó di Oyè-Àlùfáà Áárónì mú àti àwọn ìbùkún iṣẹ́ ìsìn wọn. S. Mark Palmer“Ẹ Padà sí Ọ̀dọ̀ Mi … Kí Èmi Ó Lè Wò Yín Sàn”Alàgbà Palmer kọ́ni pé kò pẹ́ jù rárá láti padà sí ọ̀dọ̀ Jésù Krístì àti ìhìnrere Rẹ̀. Sandino RomanÌgbàgbọ́: Àsopọ̀ ti Ìgbẹ́kẹ̀lé àti Ìṣòótọ́Alàgbà Roman ṣe ìtumọ̀ ìgbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí ìgbẹ́kẹ̀lé àti ìdúróṣinṣin sí Jésù Krístì ó sì kọ́ni bí a ṣe lè tọ́jú kí a sì mú ìgbàgbọ́ wa pọ̀ síi. Dale G. RenlundÌmúrasílẹ̀ Araẹni láti Pàdé OlùgbàlàAlàgbà Renlund nlo `wọn ẹ̀kọ́ látinú mẹ́ta nínú àwọn òwe Olùgbàlà láti kọ́ni bí a ti lè múra sílẹ̀ fún Bíbọ̀ Ẹ̀ẹ̀kejì. Hans T. BoomOlóotọ́ sí Ìgbàgbọ́ Tí Àwọn Òbí Wa Ti Ṣìkẹ́Alàgbà Boom kọ́ wa láti wá okun nínú ígbàgbọ́ àti ẹ̀rí ti àwọn òbí àti àwọn ará ìṣaájú wa. Dieter F. Uchtdorf“Nípa Èyí Gbogbo Ènìyàn Yíó Mọ̀ Pé Ẹ̀yin Jẹ́ Ọmọ-ẹ̀hìn Mi”Alàgbà Uchtdorf kọ́ni pé ìfẹ́ wa fún àwọn ẹlòmíràn fi jíjẹ́ ọmọ-ẹ̀hìn wa hàn, àti pé a lè rí jíjẹ́ ti ara kan àti ìrẹ́pọ̀ nínú Ìjọ ti Krístì. Abala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé Abala Ìrọ̀lẹ́ SátidéAbala Ìrọ̀lẹ́ Sátidé ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2025. Gary E. StevensonÀ Sọ̀rọ̀ Nípa KrístìAlàgbà Stevenson kọ́ni pé bí a ti ntẹ́wọ́gba àwọn ìfipè láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí Ìjọ láti mọ̀ọ́mọ̀ ṣe ayẹyẹ Ọdún Àjínde síi, a ó ri pé ìdopọ̀ wa pẹ̀lú Jésù Krístì ndàgbà si gidi. Amy A. WrightÌwọ Ni Krístì náàArábìnrin Wright kọ́ni nípa ìjẹ́pàtàkì ríran àwọn ọmọ wa lọ́wọ́ láti gbàgbọ́ nínú Jésù Krístì kí wọ́n sì dàbí Rẹ̀ síi. James R. RasbandÈtò Àánú NáàAlàgbà Rasband kọ́ni pé Ọlọ́run jẹ́ aláanú àti pé ètò ìgbàlà jẹ́ ètò àánú. Sergio R. VargasÈtò Ìtọ́sọ́nà Ọ̀run waAlàgbà Vargas kọ́ni pé fifojúsùn sọ́dọ̀ Jésù Krístì yíò rànwá lọ́wọ́ láti kojú àwọn ìjì ìgbésí ayé, yíò sì mú wa gbáradì láti padà lọ́jọ́ kan sí ilé wa ti ọ̀run. D. Todd ChristoffersonForíbalẹ̀Alàgbà D. Todd Christofferson kọ́ni nípa àwọn ìṣe tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìjọsìn; ìhùwàsí tí ó ní ìbátan sí ìjọsìn; yíyàsọ́tọ̀ ti ìjọsìn wa; àti ìnílò láti farawé àwọn Ẹni tí à njọ́sìn. Abala Òwúrọ̀ Ọjọ́-ìsinmi Abala Òwúrọ̀ Ọjọ́-ìsinmiAbala Òwúrọ̀ Ọjọ́ Ìsinmi ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2025. David A. BednarÀwọn Àkókò Ìmúpadà Ohun GbogboAlàgbà Bednar ṣe àkópọ̀ àwọn èròjà ti Ìmúpadàbọ̀sípò ìhìnrere ati Ìjọ Krístì, nínú èyí tí Ìran Àkọ́kọ́, Ìwé ti Mọ́mọ́nì, àti oyè-àlùfáà wà. Steven D. ShumwayKópa láti Múrasílẹ̀ fún Ìpadàbọ̀ KrístìAlàgbà Shumway kọ́ni pé àwọn ìpè àti àwọn ọ̀nà míràn ti sísìn nínú Ìjọ rànwá lọ́wọ́ láti dàgbà àti láti múra wa sílẹ̀ láti dúró níwájú Olùgbàlà. Tamara W. RuniaÌrònúpìwàdà Rẹ Kò Di Ẹrù Fún Jésù Krístì; Ó Tànmọ́lẹ̀ Fún Ayọ̀ Rẹ̀Arábìnrin Runia kọ́ni pé yíyẹ wa kò yípadà nígbàtí a bá ṣe àwọn àṣìṣe àti pé Olùgbàlà lóye wa Ó sì fẹ́ kí á yàn Án léraléra. Gérald CausséÌsanpadà Àwọn ÌbùkúnBíṣọ́ọ̀bù Caussé kọ́ni pé àwọn ààlà àti ìpèníjà kò ní dí àwọn ọmọ Ọlọ́run lọ́wọ́ láti gba àwọn ìbùkún tí Olúwa ṣèlérí. Gerrit W. GongÀwọn Ẹ̀bùn Nlá ti Ayérayé : Ètùtù Jésù Krístì, Àjínde, Ìmúpadàbọ̀sípò Alàgbà Gong kọ́ni pé Jésù Krístì ní ìmọ̀ wa pípé nínú ọ̀fọ̀ wa àti nínú ayọ̀ wa Ó sì npèsè wa pẹ̀lú àwọn ẹ̀bùn ètùtù, àjínde, àti ìmúpadàbọ̀sípò. John A. McCuneAyọ̀ Nípasẹ̀ Jíjẹ́ Ọmọ-ẹ̀hìn Májẹ̀múAlàgbà McCune kọ́ni ní ayọ̀ tí a lè rí nípa dídá àti pípa àwọn májẹ̀mú mọ́ pẹ̀lú Baba Ọ̀run àti títẹ̀lé Jésù Krístì. Dallin H. OaksÌrànlọ́wọ́ Àtọ̀runwá fún Ayé IkúÀàrẹ Oaks júwe onírurú àwọn ọ̀nà tí Baba Ọ̀run fi nrànwálọ́wọ́ nínú ìrìnàjò ayé ikú, bí ara ètò Rẹ̀ fún ìlọsíwájú ayérayé wa. Abala Ọ̀sán Ọjọ́-ìsinmi Abala Ọ̀sán Ọjọ́-ìsinmiAbala Ọ̀sán Ọjọ́ Ìsinmi ti Ìpàdé Àpapọ̀ Gbogbogbò Ọlọ́dọdún Ìkẹrìnléláàdọ́wàá ti Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn tí a ṣe ní Ọjọ́ Ìkẹfà sí ìkéje Oṣù Kẹrin, 2025. Ulisses SoaresỌ̀wọ̀ fún àwọn Ohun Mímọ́Alàgbà Soares kọ́ni pé níní ọ̀wọ̀ fún àwọn ohun mímọ́ yíò mú ìmoore, ìfihàn, àti ayọ̀ wá. Michael B. StrongÌfẹ́ Aláìlẹ́gbẹ́—Àmì Kan ti Jíjẹ́ Ọmọ-Ẹ̀hìn Tòótọ́Alàgbà Strong kọ́ni ní àwọn ìlànà tí ó lè ràn wá lọ́wọ́ láti mú jíjẹ́ ọmọlẹ́hìn Jésù Krístì jinlẹ̀ kí a sì dàbí Rẹ̀. Scott D. WhitingṢọ́ra Fún Ìdánwò KejìAlàgbà Whiting kọ́ni pé a gbọ́dọ̀ kọjú ìjà sí ìdánwò náà láti fi àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa pamọ́ àti pé dípò bẹ́ẹ̀ kí a wá ìrànlọ́wọ́ àtọ̀runwá. Christopher H. KimẸ Máṣe Sé Ọkàn Yín LeAlàgbà Kim kọ́ni pé a lè mú ọkàn wa rọ̀ nípa ìrònúpìwàdà, ìrẹ̀lẹ̀, àti ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa. Patrick KearonẸ Gba Ẹ̀bùn Rẹ̀Alàgbà Kearon pè wá láti gba awọn ẹ̀bùn ti Baba Ọ̀run fún wa, pàápàá ẹ̀bùn ti Ọmọ Rẹ̀ ati òtítọ́ pé a jẹ́ ọmọ Ọlọ́run. Benjamin M. Z. TaiÌfẹ́ ti Ọlọ́runAlàgbà Tai kọ́ni nípa bí a ti le ní ìmọ̀lára ìfẹ́ Ọlọ́run àti Jésù Krístì nínú ìgbé ayé wa ojoojúmọ́. Russell M. NelsonÌgbẹ́kẹ̀lé ní Ọ̀dọ̀ Ọlọ́runÀàrẹ Nelson kọ́ni pé a lè ní ìgbẹ́kẹ̀lé ní ọ̀dọ̀ Ọlọ́run bí a ti nkún ìgbésí ayé wa pẹ̀lú ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ àti ìwà-ọ̀run.