Ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti Olóyè Gbogbogbò
Ẹ̀yin arákùnrin àti arábìnrin, èmi yíò gbé àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, àwọn Àádọ́rin Agbègbè, àti àwọn Olóyè Gbogbogbò Ìjọ fún ìbò ìmúdúró yín.
Ẹ jọ́wọ́ ẹ fi àtìlẹhìn yín hàn bí ẹ ti nṣe. Bí a bá rí àwọn wọ̀nni tí wọń tako eyikeyi nínú àwọn àbá, a bèèrè pé kí ẹ kàn sí ààrẹ èèkàn yín.
A dalaba pé kí a ṣe ìmúdúró Russell Marion Nelson bí wòlíì, aríran, àti olùfihàn àti Ààrẹ Ìjọ Jésù Kristì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn; Dallin Harris Oaks bí Olùdámọ̀ràn Ìkínní; àti Henry Bennion Eyring bí Olùdámọ̀ràn Kejì nínú Àjọ Ààrẹ Ìkinní.
Àwọn wọnnì tó bá faramọ lè fihàn.
Àwọn wọnnì tó bá tàkòó, tí ẹnikẹ́ni bá wà, lè fihàn.
A dalaba pé kí ṣe imúdúró Dallin H. Oaks bí Ààrẹ Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá àti Jeffrey R. Holland bí Aṣojú Ààrẹ Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá.
Àwọn to bá faramọ, jọ̀wọ́ ṣàpẹrẹ.
Alátakò kankan tó bá wa lè fihàn.
A dalaba kí a ṣe imúdúró àwọn wọ̀nyí bí ọmọ Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá: Jeffrey R. Holland, Dieter F. Uchtdorf, David A. Bednar, Quentin L. Cook, D. Todd Christofferson, Neil L. Andersen, Ronald A. Rasband, Gary E. Stevenson, Dale G. Renlund, Gerrit W. Gong, Ulisses Soares, àti Patrick Kearon
Àwọn tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.
Alátakò kankan lè ṣe àmì bẹ́ẹ̀.
A dalaba kí a ṣe ìmúdúró àwọn olùdámọ̀ràn nínú Àjọ Ààrẹ Ìkínní àti Iyejú àwọn Àpọ́stélì Méjìlá bí àwọn wòlíì, aríran, àti olùfihàn.
Gbogbo ẹni tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.
Ìlòdì, tí ẹnìkankan bá wá, nípa irú àmì kannáà.
Àwọn Aláṣẹ Àádọ́rin Gbogbogbò wọ̀nyí ni a ó dásílẹ̀ kúrò nínú ìyànsíṣẹ́ wọn a ó sì fún wọn ní ipò àgbà, bẹ̀rẹ̀ láti Ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹ́jọ, 2025: Àwọn Alàgbà David S. Baxter, Randall K. Bennett, Kevin S. Hamilton, Rafael E. Pino, àti Jorge F. Zeballos.
Àwọn wọnnì tí wọ́n fẹ́ láti fi ìmoore hàn sí àwọn arákùnrin wọ̀nyí àti ìyàwó wọn àti ẹbí fún iṣẹ́-ìsìn ìfọkànsìn wọn nínú Ìjọ lè ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ìnawọ́ sókè.
Bákannáà a dá Alàgbà José A. Teixeira kúrò ní sínsìn bí ọmọ Àjọ Ààrẹ Àádọ́rin, bẹ̀rẹ̀ ní Ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹ́jọ, 2025.
Àwọn tí wọ́n fẹ́ láti fi ìmoore hàn sí Alàgbà Teixeira fún iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ nínú ipò èyí lè ṣe bẹ́ẹ̀.
A fi ìmoore kíyèsi àwọn Àádọ́rin Agbègbè máàrúndínláàdọ́rin tí wọ́n yíò parí iṣẹ́-ìsìn wọn àwọn tí a lè rí orúkọ́ wọn ní ibi ayélujára Ìjọ.
Àwọn wọnnì tí wọ́n fẹ́ láti darapọ̀ mọ́ wa ní fífi ìmọyì hàn sí àwọn arákùnrin wọ̀nyí àti ẹbí wọn fún àwọn ọdún iṣẹ́ ìsin ìfarajì wọn lè fihàn.
A nawọ́ ìdásílẹ̀ sí Àjọ Ààrẹ Gbogbogbò àwọn Ọ̀dọ́mọkùnrin, láti Ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹjọ, 2025 bí ìwọ̀nyí: Steven J. Lund bí Ààrẹ, Bradley R. Wilcox bí Olùdámọ̀ràn Kínní, àti Michael T. Nelson bí Olùdámọ̀ràn Kejì.
Gbogbo àwọn wọnnì tí wọ́n fẹ́ láti darapọ̀ mọ́ wa ní fífi ìmọyì hàn sí àwọn arákùnrin wọ̀nyí fún iṣẹ́ ìsin ìfọkànsìn wọn lè fihàn.
Bákannáà a dalaba kí a ṣe ìmúdúró Alàgbà Kevin R. Duncan bí ọmọ Àjọ Ààrẹ Àádọ́rin, bẹ̀rẹ̀ láti Ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹ́jọ, 2025.
Àwọn wọnnì tó bá faramọ lè fihàn.
Alátakò kankan tó bá wa lè fihàn.
A dalaba kí a ṣe ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Àádọ́rin Gbogbogbò wọ́nyí: John D. Amos, Ronald M. Barcellos, Seven C. Barlow, Kevin G. Brown, B. Corey Cuvelier, Michael Cziesla, James E. Evanson, Brik V. Eyre, Ozani Farias, Aaron T. Hall, Brian J. Holmes, Pedro X. Larreal, Clement M. Matswagothata, Eduardo F. Ortega, Edward B. Rowe, àti Wan-Liang Wu.
Gbogbo ẹni tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.
Àwọn alátakò, nípa irú àmì kannáà.
A ṣe àkíyèsí pé àwọn Àádọ́rin Agbègbè titun méjìdínlọ́gọ́ọ̀rin ni a múdúró nínú àwọn ìpàdé àpapọ̀ olórí gbogbogbò ní Ọjọ́bọ̀, Ọjọ́ Kẹ́ta Oṣù Kẹ́rin, àti lẹ́hìnnáà a kéde rẹ̀ sí orí ibi ayélujára Ìjọ. A pè yín láti ṣe ìmúdúró àwọn arákùnrin wọ̀nyí nínú yíyàn síṣẹ́ wọn titun.
Àwọn tó bá faramọ, jọ̀wọ́ fihàn.
Àwọn alátakò, nípa irú àmì kannáà.
A dalaba pé kí a ṣe ìmúdúró àwọn Àjọ Ààrẹ Ilé-Ẹ̀kọ́ Gbogbogbò Ọjọ́-ìsinmi, bẹ̀rẹ̀ láti Ọjọ́ Kínní, Oṣù Kẹ́jọ, 2024: Timothy L. Farnes bí Ààrẹ, David J. Wunderli bí Olùdámọ̀ràn Kínní, àti Sean R. Dixon bí Olùdámọ̀ràn Kejì.
Àwọn wọnnì tó bá faramọ lè fihàn.
Alátakò kankan lè ṣe àmì bẹ́ẹ̀.
A dalaba pé kí a ṣè ìmúdúró àwọn Aláṣẹ Gbogbogbò, Àádọ́rin Agbègbè, àti àwọn Olóyè Gbogbogbò bí a ṣe gbé wọn kalẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́.
Gbogbo ẹni tó bá faramọ lè ṣe bẹ́ẹ̀ nípa nínawọ́ sọ́kè.
Àwọn alátakò, to báwa.
A dúpẹ́ lọ́wọ́ yín, ẹ̀yin arákùnrin àti arábìnrin, fún ìbò ìmúdúró yín ní ìtìlẹhìn àwọn olórí Ìjọ.
Àwọn Ìyípadà sí Àwọn Àádọ́rin Agbègbè
Àwọn Àádọ́rin Agbègbè wọ̀nyí ni a ṣe ìmúdúró fún nínú abala àwọn olórí kan tí a ṣe bí ara ìpàdé àpapọ̀ gbogbogbò:
Emmanuel Rodantes G. Abraham, Jonah Akekere, Edmund L. Ang, Odilon Asevedo, Vladimir N. Astashov, Douglas W. Atwood, Ignatius K. Baidoo, Anthony John Balledos, Carlos A. Baptista, Timothy L. Barney, Marco A. Becegato, Steven L. Bodhaine, Thaddeus M. Brown, Gabriel A. Campos, Jose R. Cardenas Vanegas, Palmênio C. Castro, Robert M. Chaggares, David L. Chandler, Andrew J. Child, Carlton J. Christensen, William G. Coleman, Sean F. D. Collins, Bryan C. Crawley, Gustavo A. Cristales, Loren G. Dalton, M. Sidney Daniels, Robert L. Davis, Freeman Dickie, Moroni Dominguez Jimenez, Siale Matavaha ‘Eliesa, Robert K Ellis, James G. Fantone, Jacob C. Fish, Matthias A. Frost, W. Brett Graham, Jeremy B. Grisel, Rodney H. Hillam, Shane T. Holdaway, James A. Jarvis, Aaron R. Jenne, Jose A. Jimenez Alava, Nathan L. Johnson, H. Jason Joseph, Ronald M. Judd, Motoshige Karino, Natthapol Lattisophonkul, Roland E. Léporé, Samuel López, Ricard G. Manáhan, Arturo Martinez, Charles P. Martins, Kelend I. Mills, David E. Mouhsen, Luis Navarro, Mathias N. Niambe, Jeffery M. Nikoia, Prince S. Nyanforh, Kabemba F. Nyembo, Akingbade A. Ojo, G. Michael Ortiz, Huri Parata, Juan C. Quilantan, David A. Reyes, Matthew O. Richardson, Matthew L. Riggs, Jaime N. Rivera Jr., Stephen M. Sargent, David L. Smith, Todd B. Smith, Marco N. Sosa, Jared M. Spataro, Scott Spencer, Craig M. Teuscher, Mees Bulang-C. Tshiband, Francisco Valim, Jesus A. Vazquez Roman, Terry E. Welch, David A. Winters.
Àwọn Àádọ́rin Agbègbè wọ̀nyí ni a ó dásílẹ̀ ní tàbí ṣíwájú Ọjọ́ Ìkínní Oṣù Kẹ́jọ, 2025:
John D. Amos, Jay D. Andersen, Faapito Auapaau, Frederick K. Balli, Steven C. Barlow, Kevin W. Birch, John W. Boswell, Kevin G. Brown, J. Francisco Bührer, Suchat Chaichana, Christian C. Chigbundu, Matthew R. Clarke, L. Guido Cristobal, B. Corey Cuvelier, Edmarc R. Dumas, Brik V. Eyre, Timothy L. Farnes, Carlos A. Gabaldón, M. Andrew Galt, Vladislav Y. Gornostaev, Aaron T. Hall, Thomas Hänni, Richard I. Heaton, Broc C. Hiatt, Brian J. Holmes, David H. Huntsman, Norman Insong, Daniel Kabason, Federico M. Kähnlein, Jeffrey J. Kerr, David G. LaFrance, Marcelo Louza, Jose G. Manarin, Jeremiah J. Morgan, Mark A. Mortensen, S. Ephraim Msane, R. Pepper Murray, Eduardo F. Ortega, Nathan D. Pace, Michael M. Packer, Jorge W. Pérez, Kyrylo Pokhylko, Sergio A. Poncio, Art Rascon, Miguel A. Reynoso, Gustavo G. Rezende, Robert G. Rivarola, Edward B. Rowe, Alexey V. Samaykin, Luciano Sankari, Henry Savstrom, J. Matthew Scott, James E. Slaughter, Robert T. Smith, Ricardo Spencer, Colin C. Stauffer, David C. Stewart, Konstantin Tolomeev, Arlen M. Tumaliuan, Martin J. Turvey, Yan Carlos Vega, Paul B. Whippy, Chad R. Wilkinson, Dow R. Wilson, Markus Zarse.