Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́: Atọ́nà kan fún Ṣíṣe àwọn Yíyàn Ọ̀rọ̀ láti ọwọ́ Àjọ Ààrẹ Ìkínní Ṣe àwọn yíyàn tí ó ní ìmísí 1.Álmà 22:13Ètò Ọlọ́run wà fún yín 2.Ẹ̀kọ́ àti Àwọn Májẹ̀mú 8:2–3Ọlọ́run nfẹ́ láti báa yín sọ̀rọ̀. 3.Mósè1:39Ẹ lè ṣèrànwọ́ pẹ̀lú iṣẹ́ Ọlọ́run 4.Orin Dáfídì 147:3Jésù Krístì yíò ràn yín lọ́wọ́ 5.Gàlátíà 5:25Ẹ rìn nínú ìmọ́lẹ̀ Ọlọ́run 6.Máttéù 22:37–40Fẹ́ràn Ọlọ́run, Fẹ́ ọmọnìkéjì rẹ 7.Ẹ̀kọ́ àti Àwọn Májẹ̀mú 84:20Àwọn ìlànà àti májẹ̀mú nfún wa ní ààyè sí àwọn ìbùkún Ọlọ́run. 8.Ẹ̀kọ́ ati àwọn Májẹ̀mú 95:8Àwọn ìlànà àti májẹ̀mú tẹ́mpìlì nfún yín ní ààyè títóbijù sí àwọn ìbùkún Ọlọ́run. 9.Máttéù 16:18–19Ẹ di alábùkúnfún nípa àwọn kọ́kọ́rọ́ àti àṣẹ oyè àlùfáà 10.1 Kọ́ríntì 6:18–20Ara yín jẹ́ mímọ́ 11.Jòhánnù 8:32Òtítọ́ yíò sọ yín di òmìnira 12.Ẹ̀kọ́ àti Àwọn Májẹ̀mú 101:36Jésù Krístì nmú ayọ̀ wá Àlẹ̀mọ́ Atọ́kaNípa kíni …?