àwọn ọ̀dọ́
Nípa kíni ?


Nípa kíni …?

Ní ìsàlẹ̀ ni àwọn àkọlé tí ẹ lè ní ìbèèrè nípa rẹ̀. Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́ kò mẹ́nuba gbogbo wọn nípa orúkọ, ṣùgbọ́n ó kọ́ àwọn òtítọ́ ayérayé tí ó lè ràn yín lọ́wọ́ láti ṣe àwọn ìpinnu nípa àwọn àkọlé wọ̀nyí. Ẹ ó rí àwọn òtítọ́ wọ̀nyí ní orí àwọn ewé tí a tò sísàlẹ̀.