Làìhónà Oṣù Kínní 2026 David A. BednarAlabápin ti Iwà-ẹ̀dá Atọ̀runwáAlàgbà Bednar kọ́ni pé àwọn ẹ̀mí wa níláti wúsókè pẹ̀lú ìmoore bí a ṣe ngbèrò ètò ìgbàlà, ìràpadà, ìmúpadàsípò, àánú, àti ìdùnnú nlá ti Ọlọ́run. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Àwọn Àjọ Ààrẹ Gbogbogbò Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin àti Ọ̀dọ́mọkùnrinRìn pẹ̀lú MiÀwọn ọ̀rọ̀ láti ọwọ́ àwọn Àjọ Ààrẹ Gbogbogbò Àwọn Ọ̀dọ́ Obìnrin àti Àwọn Ọ̀dọ́mọkùnrin nípa Àkórí Ọ̀dọ́ 2026. Fríẹ́ndì Ádámù àti ÉfàẸ ka ìtàn nípa Ádámù àti Éfà nínú Ọgbà Édẹ́nì.