Oṣù Keje 2025 Gary E. StevensonRí Ayọ̀ Nínu Ìrìnàjò ÌhìnrereAlàgbà Stevenson pe àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn láti ṣe àbápín àwọn èso ìhìnrere àti láti ní ìmọ̀lára ayọ̀ ní ayé yí bí wọ́n ṣe nrìn ìrìnàjò sí ìyè ayérayé. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ David A. EdwardsLẹ́hìn Ayé Yìí: Àwọn Ìdáhùn sí Àwọn Ìbèèrè Díẹ̀Ní ìhín ni àwọn ìdáhùn sí àwọn ìbèèrè díẹ̀ tí àwọn ọmọ Ìjọ lè ní nípa ìgbé ayé lẹ́hìn ikú. Fríẹ́ndì Àwọn Ìtàn Ìwé Mímọ́: Àwọn Àpóstélì Sin Míṣọ̀n kan lọ sí Great BritainKa ìtàn kan nípa bí àwọn Àpóstélì ti Ìjọ tí a múpadàbọ̀sípò ṣe borí ìnira láti sin àwọn míṣọ̀n ní Great Britain.