Oṣù Kẹfà 2025 Dale G. RenlundA Ntẹ̀lé Jésù Krístì nípa Dídarapọ̀ mọ́ Ọ nínú Iṣẹ́ Rẹ̀Alàgbà Renlund pe àwọn Ènìyàn-Mímọ́ Ọjọ́ Ìkẹhìn láti fi ìtara kópa nínú iṣẹ́ Olúwa nípa fífojúsùn sórí àwọn èrèdí Rẹ̀, pípa àwọn òfin Rẹ̀ mọ́, àti níní ìfẹ́ ẹnìkan sí òmíràn. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Báwo ni mo ṣe lè mọ̀ pé mo ti ronúpíwàdà nítòótọ́ àti pé a ti dáríjì mí?Ìdáhùn sí ìbéèrè náà: “Báwo ni mo ṣe lè mọ̀ pé mo ti ronúpíwàdà nítòótọ́ àti pé a ti dáríjì mí?” Fríẹ́ndì Àwọn Ìtàn Ìwé Mímọ́: Kíkọ́ Tẹ́mpílì Kirtland.Ka ìtàn kan nípa àwọn ènìyàn mímọ́ tí wọ́n nkọ́ Tẹ́mpílì Kirtland.