Oṣù Kejì 2025 Dieter F. Uchtdorf“Èmi Ó Wò Wọ́n Sàn”Alàgbà Uchtdorf kọ́ni pé iṣẹ́ ìránṣẹ́ ìwòsàn Olùgbàlà jẹ́ ìṣíwájú àtọ̀runwá àti ìlérí kan nípa ìwòsàn pípẹ́ ti ara àti ti ẹ̀dùn ọkàn tí yíò wá sọ́dọ̀ ẹnìkọ̀ọ̀kan wa nínú Àjínde. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ David DicksonÌrànlọ́wọ́ láti inú Orísun Pípé kanÈyíówù ìlàkàkà tí ó lè wà ní ìlòdì sí yín, Jésù Krístì yíò ràn yín lọ́wọ́ bí ẹ ti nyípadà sí I. Fríẹ́ndì Joseph Smith Gba Àwọn Àwo IdẹẸ ka ìtàn nípa Joseph Smith tí ó ngba àwọn àwo idẹ.