Làìhónà Oṣù Kẹrin 2026 Neil L. AndersenÌṣẹ́gun ti Àyànfẹ́ Wa OlùgbàlàAlàgbà Andersen jẹ́ ẹ̀rí pé Jésù Krístì já àwọn ẹ̀wọ̀n ìgbèkùn ayéraye ti ikú fún gbogbo ẹnití ó ti gbé rí tàbí yíò gbé lórí ilẹ̀ ayé. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ David DicksonLẹ́hìn Àwọn Àṣìṣe Yín—Àní Àwọn TítóbiA lè kọ́ púpọ̀ láti ọ̀dọ̀ Àpóstélì Pétérù nípa Olùgbàlà, Ètùtù Rẹ̀, kí ẹ sì gbíyànjú lẹ́ẹ̀kansi. Fríẹ̀ndì Ìtàn Ìwé Mímọ́: Àjọ ÌrékọjáẸ ka ìtàn nípa Mósè tí ó ndarí àwọn Ọmọ Ísráẹ́lì jáde ní Égípítì àti yíyàkúrò ìyanilẹ́nu Òkun Pupa.