Làìhónà Oṣù Kẹwàá 2025 Ronald A. RasbandÀwọn Májẹ̀mú, Agbára, àti àwọn ÌléríAlàgbà Rasband jẹ́ ẹ̀rí pé tẹ́mpìlì ni àárín-gbungbun ìlérí sí agbára ati ààbò sí àwọn olóòọ́tọ́ ṣíwájú Ìpadàbọ̀ Ẹẹ̀kejì ti Olúwa Jésù Krístì. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Kínìdí tí Olúwa fi ní Ìjọ kan?Ìdáhùn ránpẹ́ sí ìbèèrè náà: “Kínìdí tí Olúwa fi ní Ìjọ kan?” Fríẹ́ndì Àwọn Ìtàn Ìwé Mímọ́: Jane Manning Rin Ìrìnàjò lọ sí NauvooẸ ka ìtàn nípa Jane Manning àti ẹbí rẹ̀ tí wọ́n nrin ọgọọgọ́ọ̀rún máìlì lọ sí Nauvoo láti kórajọ pẹ̀lú àwọn Ènìyàn Mímọ́.