Oṣù Kẹta 2025 Neil L. AndersenBaba Ọ̀run Fẹ́ Bá Yín Sọ̀rọ̀Alàgbà Andersen kọ́ni pé Baba Ọ̀run yío bá wa sọ̀rọ̀ bí a bá ké pè É nínú àdúrà, fi etí sílẹ̀ fún ohùn Rẹ̀, tí a sì ní ọkàn tó ńgbàgbọ́. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Báwo ni a ṣe le gbé nínú ayé kí a sì “gbé àwọn ohun ti ayé yìí sí ẹ̀gbẹ́ kan”?Ìdáhùn kan sí ìbéèrè: Báwo ni a ṣe le gbé nínú ayé kí a sì “gbé àwọn ohun ti ayé yìí sí ẹ̀gbẹ́ kan”? Fríẹ́ndì Àwọn Ìtàn inu Ìwé-mímọ́: A Mú Oyè-àlùfáà Padàbọ̀sípòẸ ka ìtàn kan nípa Joseph Smith tí ó nṣe ìrìbọmi tí ò sì ngba oyè-àlùfáà.