Oṣù Kínní 2025 Patrick KearonÌròhìn Rere ti Ìfẹ́ àti Ayọ̀Alàgbà Kearon pín ayọ̀ àti àwọn ìbùkún tí à ngbádùn nítorí ìmúpadàbọ̀sípò Ìjọ Olùgbàlà. Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Àwọn Àjọ Ààrẹ Gbogbogbò Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin àti Ọ̀dọ́mọkùnrinWò ọ̀dọ̀ KrístìÀwọn Àjọ Ààrẹ Gbogbogbò Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin àti Ọ̀dọ́mọkùnrin sọ̀rọ̀ nípa ohun tí Àkórí fún Àwọn Ọ̀dọ́ ní 2025, Wo ọ̀dọ̀ Krístì, túmọ̀sí fún wọn. Fríẹ́ndì Àwọn Ìtàn Ìwé-mímọ́: Ìran Àkọ́kọ́Ẹ ka ìtàn nípa Ìràn Ìkínní ti Joseph Smith.