“Ó Wá,” Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́, Oṣù Kejìlá 2021.
Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́, Oṣù Kejìlá 2021.
Ó Wá
Ẹkọ́ àti Àwọn Májẹ̀mú jẹri pé Jésù Krístì wá sí ayé Ó sì kọwa ní ẹnití Òun í ṣe àti ohun tí Ó mú wá fún gbogbo ènìyàn.
A Bí I Ní Ilẹ̀-ayé.
Gbígbé kalẹ̀, láti ọwọ́ Jenedy Paige
Ó Wá láti Ṣe Ìfẹ́ ti Baba
Ní Ilẹ̀-ayé bí Ó Ti Wà ní Ọrun, láti ọwọ́ Justin Kunz
Ó Kọ́ ẹ̀kọ́ Ó sì Dàgbà
Ọmọ náà sì Dàgbà Ó sì Di Alágbára nínú Ẹ̀mí, láti ọwọ́ Walter Rane
Ó Wá láti Ra Gbogbo Ènìyàn Padà
Krísti ní Gẹ́tsémánì, láti ọwọ́ Michael Malm
Ó Rán Àwọn Míràn Láti Jẹri nípa Rẹ̀
Àpèjúwe láti ọwọ́ Justin Kunz
Òun ni Ìmọ́lẹ̀.
Ọ̀dọ́ Àgùtàn Kékeré, lati ọwọ́ Jenedy Paige
© 2021 nípasẹ̀ Intellectual Reserve, Inc. Gbogbo àwọn ẹ̀tọ́ ni a fi pamọ́. A tẹ̀ẹ́ ní USA. Àṣẹ Èdè Gẹẹsì: 6/19. Àṣẹ Ìyírọ̀padà-èdè: 6/19. Ìyírọ̀padà-èdè ti Fún Okun Àwọn Ọ̀dọ́ Oṣooṣù, Oṣù Kejìlá 2021. Yoruba. 17476 000